MC Freedom (Ademola Moses)
General Manager
About MC
My Shows
Tinu Tode Iroyin
Ẹ má bà a lọ̀! Gbọ́ ìròyìn tuntun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ gbogbo ní Tinu Tode Iroyin. Láti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ń ṣẹlẹ̀ lókèèrè dé ti ilẹ̀ wa, pẹ̀lú àtúpalẹ̀ tó jinlẹ̀, ìròyìn wa máa jẹ́ kó rọrùn fún ẹ láti mọ ohun tó ṣẹlẹ̀. Ẹ jẹ́ ká pàdé ní Mọ́ńdé sí Furaidé, 9 AM – 10 AM fún ìròyìn tó péye
Learn More →
Idan Ori Odan
The ultimate sports show where àjọṣe àti ìdárayá kọ́ lórí pẹpẹ. From bọọlu, báskẹ́tìbọọ̀lù, to èrè orí kómpútà, we dey gbádùn gbogbo ìtàn, àtúpalẹ̀, àti ìròyìn tó gbẹ̀kẹ̀lé. Ẹ̀yin ọmọ bíbí ẹlẹ́sẹ̀ àti olùṣèrè, ẹ jẹ́ ká bà á lọ!
Learn More →
L’abe Igi Oronbo
L’abe Igi Oronbo is your early morning escape into rich storytelling, life lessons, and interactive Q&A sessions. Tune in Monday to Friday, 5:30 AM – 6:30 AM
Learn More →
L’agbo Amuludun
L’agbo Amuludun with Ademola Moses serves it hot and unfiltered. Tune in Tuesdays, 7:30 PM – 8:30 PM for back-to-back vibes, juicy updates, and the voices of the stars you love. Amuludun no dey dull!
Learn More →